Ìṣe Àwọn Aposteli 12:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ tí ọba dá fún wọn, Hẹrọdu yọ dé pẹlu aṣọ ìgúnwà rẹ̀, ó jókòó lórí ìtẹ́ rẹ̀. Ó wá bá àwọn eniyan náà sọ̀rọ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:12-25