Ìṣe Àwọn Aposteli 12:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Hẹrọdu wá Peteru títí, ṣugbọn kò rí i. Lẹ́yìn tí ó ti wádìí lẹ́nu àwọn ẹ̀ṣọ́ tán, ó ní kí wọ́n pa wọ́n.Ni Hẹrọdu bá kúrò ní Judia, ó lọ sí Kesaria, ó lọ gbé ibẹ̀ fún ìgbà díẹ̀.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:12-25