Ìṣe Àwọn Aposteli 12:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá fi ọwọ́ ṣe àmì sí wọn kí wọ́n dákẹ́; ó ròyìn fún wọn bí Oluwa ti ṣe mú òun jáde kúrò lẹ́wọ̀n. Ó ní kí wọn ròyìn ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún Jakọbu ati fún àwọn arakunrin yòókù. Ó bá jáde, ó lọ sí ibòmíràn.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:11-22