Ìṣe Àwọn Aposteli 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò náà Hẹrọdu ọba bẹ̀rẹ̀ sí ṣe inúnibíni sí àwọn kan ninu ìjọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Ìṣe Àwọn Aposteli 12:1-5