Ìṣe Àwọn Aposteli 11:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo tẹjú mọ́ ọn láti wo ohun tí ó wà ninu rẹ̀. Mo bá rí àwọn ẹranko ẹlẹ́sẹ̀ mẹrin ati àwọn ẹranko ìgbẹ́ ati àwọn ẹranko tí ń fi àyà wọ́, ati àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:3-7