Ìṣe Àwọn Aposteli 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Peteru bá tẹnu bọ̀rọ̀, ó ro gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀ fún wọn lẹ́sẹẹsẹ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:3-7