Ìṣe Àwọn Aposteli 11:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó rí i, ó mú un wá sí Antioku; fún ọdún kan gbáko ni àwọn mejeeji fi wà pẹlu ìjọ, tí wọn ń kọ́ ọpọlọpọ eniyan lẹ́kọ̀ọ́. Ní Antioku ni a ti kọ́ pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Kristi ní “Kristẹni.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:16-30