Ìṣe Àwọn Aposteli 11:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Banaba jẹ́ eniyan rere, tí ó kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, tí ó sì gbàgbọ́ tọkàntọkàn, ọ̀pọ̀ eniyan ni ó di onigbagbọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:14-30