Ìṣe Àwọn Aposteli 11:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo ti bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀rọ̀ ni Ẹ̀mí Mímọ́ bá bà lé wọn bí ó ti bà lé wa ní àkọ́kọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:5-20