Ìṣe Àwọn Aposteli 11:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀mí wá sọ fún mi pé kí n bá wọn lọ láì kọminú. Mẹfa ninu àwọn arakunrin bá mi lọ. A bá wọ ilé ọkunrin náà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:8-20