Ìṣe Àwọn Aposteli 11:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹẹmẹta ni ó ṣẹlẹ̀ bẹ́ẹ̀, ni nǹkankan bá tún fa gbogbo wọn pada sí ọ̀run.

Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Ìṣe Àwọn Aposteli 11:8-14