Ìṣe Àwọn Aposteli 10:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ keji, bí wọ́n ti ń bá ìrìn àjò wọn lọ, tí wọ́n súnmọ́ Jọpa, Peteru gun òkè ilé lọ láti gbadura ní nǹkan agogo mejila ọ̀sán.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:3-18