Ìṣe Àwọn Aposteli 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí angẹli tí ó ń bá a sọ̀rọ̀ ti lọ tán, ó pe meji ninu àwọn iranṣẹ rẹ̀ ati ọmọ-ogun olùfọkànsìn kan, ọ̀kan ninu àwọn tí ó máa ń dúró tì í tímọ́tímọ́.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:1-8