Ìṣe Àwọn Aposteli 10:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii wá rán àwọn kan lọ sí Jọpa, kí wọn lọ pe ẹnìkan tí ń jẹ́ Simoni, tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ Peteru, kí ó wá.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:1-11