Ìṣe Àwọn Aposteli 10:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe gbogbo eniyan ni ó rí i bíkòṣe àwọn ẹlẹ́rìí tí Ọlọrun ti yàn tẹ́lẹ̀, àwa tí a bá a jẹ, tí a bá a mu lẹ́yìn tí ó jinde kúrò ninu òkú.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:36-45