Ìṣe Àwọn Aposteli 10:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí tí mo ṣe wá láì kọminú nìyí nígbà tí o ranṣẹ sí mi. Mo wá fẹ́ mọ ìdí rẹ̀ tí o fi ranṣẹ sí mi.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:27-39