Ìṣe Àwọn Aposteli 10:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Peteru dé ìsàlẹ̀, ó wí fún àwọn ọkunrin náà pé, “Èmi tí ẹ̀ ń wá nìyí, kí ni ẹ̀ ń fẹ́ o?”

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:13-27