Ìṣe Àwọn Aposteli 10:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Peteru ti ń ronú lórí ìran yìí, Ẹ̀mí sọ fún un pé, “Àwọn ọkunrin mẹta ń wá ọ.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:9-22