Ìṣe Àwọn Aposteli 10:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìran tí Peteru rí yìí rú u lójú. Bí ó ti ń rò ó pé kí ni ìtumọ̀ ohun tí òun rí yìí, àwọn tí Kọniliu rán sí i ti wádìí ibi tí ilé Simoni wà, wọ́n ti dé ẹnu ọ̀nà.

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:14-26