Ìṣe Àwọn Aposteli 10:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Peteru dáhùn pé, “Èèwọ̀ Oluwa! N kò jẹ ẹrankẹ́ran tabi ẹran àìmọ́ kan rí.”

Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:8-18