Ìṣe Àwọn Aposteli 1:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá ṣẹ́ gègé. Gègé bá mú Matiasi. Ó bá di ọ̀kan ninu àwọn aposteli mọkanla.

Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Ìṣe Àwọn Aposteli 1:18-26