Ìṣe Àwọn Aposteli 1:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbadura pé, “Ìwọ Oluwa, Olùmọ̀ràn gbogbo eniyan, fi ẹni tí o bá yàn ninu àwọn mejeeji yìí hàn,

Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Ìṣe Àwọn Aposteli 1:13-26