Ìṣe Àwọn Aposteli 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọ̀rọ̀ náà rí bí ó ti wà ní àkọsílẹ̀ ninu Ìwé Orin Dafidi pé,‘Kí ibùgbé rẹ̀ di ahoro,kí ẹnikẹ́ni má gbé ibẹ̀.’Ati pé,‘Kí á fi ipò rẹ̀ fún ẹlòmíràn.’

Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Ìṣe Àwọn Aposteli 1:19-21-22