Ìṣe Àwọn Aposteli 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n wọ inú ilé, wọ́n lọ sí iyàrá òkè níbi tí wọn ń gbé. Àwọn tí wọ́n jọ ń gbé ni Peteru, Johanu, Jakọbu, Anderu, Filipi, Tomasi, Batolomiu, Matiu, Jakọbu ọmọ Alfeu, Simoni ti ẹgbẹ́ Seloti ati Judasi ọmọ Jakọbu.

Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Ìṣe Àwọn Aposteli 1:11-15