Hosia 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli kò ní dúró ní ilẹ̀ OLUWA mọ́; Efuraimu yóo pada sí Ijipti, wọn yóo sì jẹ ohun àìmọ́ ní ilẹ̀ Asiria.

Hosia 9

Hosia 9:1-7