Hosia 9:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun mi yóo pa wọ́n run, nítorí pé wọn kò fetí sí ọ̀rọ̀ rẹ̀; wọn yóo di alárìnkiri láàrin àwọn orílẹ̀-èdè.

Hosia 9

Hosia 9:16-17