Hosia 9:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Fún wọn ní nǹkankan, OLUWA, OLUWA, kí ni ò bá tilẹ̀ fún wọn? Jẹ́ kí oyún máa bàjẹ́ lára obinrin wọn, kí ọmú wọn sì gbẹ.

Hosia 9

Hosia 9:10-17