Hosia 8:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Oriṣa ẹgbọ̀rọ̀ mààlúù kì í ṣe Ọlọrun, iṣẹ́ ọwọ́ eniyan ni, a óo sì rún ti Samaria wómúwómú.

Hosia 8

Hosia 8:2-13