Hosia 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí Efuraimu ti tẹ́ ọpọlọpọ pẹpẹ láti dẹ́ṣẹ̀ níbẹ̀, wọ́n ti di pẹpẹ ẹ̀ṣẹ̀ dídá fún un.

Hosia 8

Hosia 8:7-14