Hosia 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Iná ọ̀tẹ̀ wọn ń jò bí iná ojú ààrò, inú wọn ń ru, ó ń jó bí iná ní gbogbo òru; ní òwúrọ̀, ó ń jó lálá bí ahọ́n iná.

Hosia 7

Hosia 7:1-14