Hosia 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí pé, “Àwọn eniyan ń dá ọba ninu dùn, nípa ìwà ibi wọn, wọ́n ń mú àwọn ìjòyè lóríyá nípa ìwà ẹ̀tàn wọn.

Hosia 7

Hosia 7:1-8