Hosia 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, èmi ni mo tọ́ wọn dàgbà, tí mo sì fún wọn lókun, sibẹsibẹ wọ́n ń gbèrò ibi sí mi.

Hosia 7

Hosia 7:7-16