Hosia 7:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Efuraimu dàbí ẹyẹ àdàbà, ó jẹ́ òmùgọ̀ ati aláìlóye, ó ń pe Ijipti fún ìrànlọ́wọ́, o ń sá tọ Asiria lọ.

Hosia 7

Hosia 7:9-16