Hosia 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Efuraimu yóo di ahoro ní ọjọ́ ìjìyà; mo ti fi ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ dájúdájú hàn, láàrin àwọn ẹ̀yà Israẹli.

Hosia 5

Hosia 5:5-11