Hosia 5:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo mú mààlúù ati aguntan wá, láti fi wá ojurere OLUWA, ṣugbọn wọn kò ní rí i; nítorí pé, ó ti fi ara pamọ́ fún wọn.

Hosia 5

Hosia 5:4-8