Hosia 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹ óo fẹsẹ̀ kọ lojumọmọ, ẹ̀yin wolii pàápàá yóo kọsẹ̀ lóru, n óo sì pa Israẹli, ìyá yín run.

Hosia 4

Hosia 4:1-12