Hosia 3:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, àwọn ọmọ Israẹli yóo wà fún ọjọ́ gbọọrọ láìní ọba tabi olórí láìsí ẹbọ tabi ère, láìsí aṣọ efodu tabi ère terafimu.

Hosia 3

Hosia 3:3-5