Hosia 14:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun ní,“N óo gba ìwà aiṣootọ lọ́wọ́ wọn,n óo fẹ́ wọn tọkàntọkàn,nítorí n kò bínú sí wọn mọ́.

Hosia 14

Hosia 14:1-9