Hosia 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ yipada nípa agbára Ọlọrun yín, ẹ di ìfẹ́ ati ìdájọ́ òdodo mú, kí ẹ sì dúró de Ọlọrun yín nígbà gbogbo.

Hosia 12

Hosia 12:1-8