Hosia 11:6 BIBELI MIMỌ (BM)

A óo fi idà run àwọn ìlú wọn, irin ìdábùú ìlẹ̀kùn bodè wọn yóo ṣẹ́, a óo sì pa wọ́n run ninu ibi ààbò wọn.

Hosia 11

Hosia 11:3-11