Hosia 10:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń fọ́nnu lásán; wọ́n ń fi ìbúra asán dá majẹmu; nítorí náà ni ìdájọ́ ṣe dìde sí wọn bíi koríko olóró, ní poro oko.

Hosia 10

Hosia 10:2-10