Heberu 6:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọ̀nà kan náà, nígbà tí Ọlọrun fẹ́ fihàn gbangba fún àwọn ajogún ìlérí wí pé èrò òun kò yipada, ó ṣe ìlérí, ó sì fi ìbúra tì í.

Heberu 6

Heberu 6:15-20