Heberu 5:11 BIBELI MIMỌ (BM)

A ní ọ̀rọ̀ pupọ láti sọ fun yín nípa Mẹlikisẹdẹki yìí. Ọ̀rọ̀ náà ṣòro láti túmọ̀ nígbà tí ọkàn yín ti le báyìí.

Heberu 5

Heberu 5:3-14