Heberu 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwa tí a gbàgbọ́ ni a wọ inú ìsinmi náà. Nígbà tí Ọlọrun sọ pé,“Mo búra pẹlu ibinu pé,wọn kò ní wọ inú ìsinmi mi.”Ó sọ bẹ́ẹ̀ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti parí iṣẹ́ rẹ̀ láti ìpìlẹ̀ ayé.

Heberu 4

Heberu 4:1-11