Heberu 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ẹ̀dá kan tí ó lè fara pamọ́ níwájú rẹ̀. Gbogbo nǹkan ṣípayá kedere níwájú Ọlọrun, ẹni tí a óo jíyìn iṣẹ́ wa fún.

Heberu 4

Heberu 4:11-15