Heberu 4:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹni tí ó bá wọ inú ìsinmi rẹ̀ ti sinmi ninu iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti sinmi ninu tirẹ̀.

Heberu 4

Heberu 4:4-14