Heberu 2:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ó dájú pé, kì í ṣe àwọn angẹli ni ó wá ṣe ìrànlọ́wọ́ fún bíkòṣe àwọn ọmọ Abrahamu.

Heberu 2

Heberu 2:6-18