Heberu 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ó yẹ kí á túbọ̀ ṣe akiyesi àwọn ohun tí à ń gbọ́, kí á má baà gbá wa lọ bí ìgbà tí odò gbá nǹkan lọ.

Heberu 2

Heberu 2:1-3