Heberu 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má gbàgbé láti máa ṣe àlejò nítorí nípa àlejò ṣíṣe àwọn ẹlòmíràn ti ṣe àwọn angẹli lálejò láìmọ̀ pé angẹli ni wọ́n.

Heberu 13

Heberu 13:1-4