Heberu 12:28-29 BIBELI MIMỌ (BM)

28. Nítorí náà, níwọ̀n ìgbà tí ẹ ti gba ìjọba tí kò ṣe é mì, ẹ jẹ́ kí á dúpẹ́. Ẹ jẹ́ kí á sin Ọlọrun bí ó ti yẹ pẹlu ọ̀wọ̀ ati ẹ̀rù;

29. nítorí iná ajónirun ni Ọlọrun wa.

Heberu 12